Àìsáyà 45:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àmọ́ Jèhófà máa gba Ísírẹ́lì là, ìgbàlà náà sì máa jẹ́ títí láé.+ Ojú ò ní tì yín, ìtìjú ò sì ní bá yín títí ayé.+
17 Àmọ́ Jèhófà máa gba Ísírẹ́lì là, ìgbàlà náà sì máa jẹ́ títí láé.+ Ojú ò ní tì yín, ìtìjú ò sì ní bá yín títí ayé.+