Sáàmù 31:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin tí ẹ jẹ́ adúróṣinṣin sí i!+ Jèhófà ń dáàbò bo àwọn olóòótọ́,+Àmọ́ ó máa ń san èrè tó kún rẹ́rẹ́ fún àwọn tó bá ń gbéra ga.+
23 Ẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin tí ẹ jẹ́ adúróṣinṣin sí i!+ Jèhófà ń dáàbò bo àwọn olóòótọ́,+Àmọ́ ó máa ń san èrè tó kún rẹ́rẹ́ fún àwọn tó bá ń gbéra ga.+