ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 10:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àwọn tó ń gbé ìlànà tó ń pani lára kalẹ̀ gbé,+

      Àwọn tó ń ṣe òfin tó ń nini lára ṣáá,

  • Dáníẹ́lì 6:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Gbogbo àwọn òṣìṣẹ́ ọba, àwọn aṣíwájú, àwọn baálẹ̀, àwọn olóyè jàǹkàn-jàǹkàn àti àwọn gómìnà ti gbìmọ̀ pọ̀ láti fi àṣẹ kan lélẹ̀ látọ̀dọ̀ ọba, kí wọ́n sì kà á léèwọ̀* pé, láàárín ọgbọ̀n (30) ọjọ́, ẹnikẹ́ni tó bá béèrè nǹkan lọ́wọ́ ọlọ́run tàbí èèyàn èyíkéyìí yàtọ̀ sí ìwọ ọba, ká ju onítọ̀hún sínú ihò kìnnìún.+

  • Ìṣe 5:27, 28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Torí náà, wọ́n mú wọn wá, wọ́n sì ní kí wọ́n dúró níwájú Sàhẹ́ndìrìn. Àlùfáà àgbà wá bi wọ́n ní ìbéèrè, 28 ó sì sọ pé: “A kìlọ̀ fún yín gidigidi pé kí ẹ má ṣe máa kọ́ni nípa orúkọ yìí,+ síbẹ̀, ẹ wò ó! ẹ ti fi ẹ̀kọ́ yín kún Jerúsálẹ́mù, ẹ sì pinnu láti mú ẹ̀jẹ̀ ọkùnrin yìí wá sórí wa.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́