Ẹ́kísódù 23:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Má ṣe gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀, torí àbẹ̀tẹ́lẹ̀ máa ń dí àwọn tó ríran kedere lójú, ó sì lè mú kí àwọn olódodo yí ọ̀rọ̀ po.+
8 “Má ṣe gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀, torí àbẹ̀tẹ́lẹ̀ máa ń dí àwọn tó ríran kedere lójú, ó sì lè mú kí àwọn olódodo yí ọ̀rọ̀ po.+