Jòhánù 3:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Ẹni tó bá ń ní ìgbàgbọ́ nínú Ọmọ ní ìyè àìnípẹ̀kun;+ ẹni tó bá ń ṣàìgbọràn sí Ọmọ kò ní rí ìyè,+ àmọ́ ìbínú Ọlọ́run wà lórí rẹ̀.+
36 Ẹni tó bá ń ní ìgbàgbọ́ nínú Ọmọ ní ìyè àìnípẹ̀kun;+ ẹni tó bá ń ṣàìgbọràn sí Ọmọ kò ní rí ìyè,+ àmọ́ ìbínú Ọlọ́run wà lórí rẹ̀.+