Ẹ́kísódù 20:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àwọn èèyàn náà ò kúrò ní ọ̀ọ́kán níbi tí wọ́n dúró sí, àmọ́ Mósè sún mọ́ ìkùukùu* tó ṣú dùdù náà níbi tí Ọlọ́run tòótọ́ wà.+
21 Àwọn èèyàn náà ò kúrò ní ọ̀ọ́kán níbi tí wọ́n dúró sí, àmọ́ Mósè sún mọ́ ìkùukùu* tó ṣú dùdù náà níbi tí Ọlọ́run tòótọ́ wà.+