ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Onídàájọ́ 5:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Àwọn òkè yọ́* níwájú Jèhófà,+

      Títí kan Sínáì, níwájú Jèhófà,+ Ọlọ́run Ísírẹ́lì.+

  • Náhúmù 1:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Àwọn òkè ńlá mì tìtì nítorí rẹ̀,

      Àwọn òkè kéékèèké sì yọ́.+

      Ayé á ru sókè nítorí ojú rẹ̀,

      Àti ilẹ̀ pẹ̀lú gbogbo àwọn tó ń gbé orí rẹ̀.+

  • Hábákúkù 3:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Ó dúró jẹ́ẹ́, ó sì mi ayé jìgìjìgì.+

      Ó wo àwọn orílẹ̀-èdè, ó sì mú kí wọ́n gbọ̀n rìrì.+

      Ó fọ́ àwọn òkè tó ti wà tipẹ́,

      Àwọn òkè àtayébáyé sì tẹrí ba.+

      Òun ló ni àwọn ọ̀nà àtijọ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́