-
Diutarónómì 8:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 “Tí ẹ bá gbàgbé Jèhófà Ọlọ́run yín pẹ́nrẹ́n, tí ẹ wá ń tọ àwọn ọlọ́run míì lẹ́yìn, tí ẹ̀ ń sìn wọ́n, tí ẹ sì ń forí balẹ̀ fún wọn, mo ta kò yín lónìí pé ó dájú pé ẹ máa pa run.+
-