ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 49:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Ó sọ pé: “Ti pé o jẹ́ ìránṣẹ́ mi nìkan ò tó,

      Láti gbé àwọn ẹ̀yà Jékọ́bù dìde,

      Kí o sì mú àwọn tí a dá sí lára Ísírẹ́lì pa dà.

      Mo tún ti fi ọ́ ṣe ìmọ́lẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè,+

      Kí ìgbàlà mi lè dé gbogbo ayé.”+

  • Ìṣe 28:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Torí náà, ẹ jẹ́ kó yé yín pé, ìgbàlà yìí tó wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni a ti kéde fún àwọn orílẹ̀-èdè;+ ó dájú pé wọ́n á fetí sí i.”+

  • Róòmù 10:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Àmọ́ mo béèrè pé, Ṣé wọn ò gbọ́ ni? Wọ́n kúkú gbọ́. Torí, ní tòótọ́, “ohùn wọn ti dún jáde lọ sí gbogbo ayé, iṣẹ́ tí wọ́n ń jẹ́ sì ti dé ìkángun ilẹ̀ ayé tí à ń gbé.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́