ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 10:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “Bákan náà, ní àwọn ọjọ́ ayọ̀+ yín, ìyẹn, nígbà àwọn àjọyọ̀+ yín àti ní ìbẹ̀rẹ̀ àwọn oṣù yín, kí ẹ fun àwọn kàkàkí náà sórí àwọn ẹbọ sísun+ àti àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀+ yín; wọ́n máa jẹ́ ohun ìrántí fún yín níwájú Ọlọ́run yín. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run+ yín.”

  • 1 Kíróníkà 15:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà bọ̀ pẹ̀lú igbe ayọ̀+ àti pẹ̀lú ìró ìwo àti kàkàkí+ pẹ̀lú síńbálì, wọ́n sì ń fi àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti háàpù+ kọrin sókè.

  • 2 Kíróníkà 29:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Nígbà náà, Hẹsikáyà pàṣẹ pé kí wọ́n rú ẹbọ sísun náà lórí pẹpẹ.+ Nígbà tí ẹbọ sísun náà bẹ̀rẹ̀, orin Jèhófà bẹ̀rẹ̀, kàkàkí sì bẹ̀rẹ̀ sí í dún, wọ́n ń tẹ̀ lé àwọn ohun ìkọrin Dáfídì ọba Ísírẹ́lì.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́