Jóòbù 36:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Kò ní dá ẹ̀mí àwọn ẹni burúkú sí,+Àmọ́ ó ń dá ẹjọ́ àwọn tí ìyà ń jẹ bó ṣe tọ́.+