1 Sámúẹ́lì 7:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Sámúẹ́lì wá mú ọ̀dọ́ àgùntàn kan tó ṣì ń mu ọmú, ó sì fi rú odindi ẹbọ sísun+ sí Jèhófà; Sámúẹ́lì ké pe Jèhófà pé kó ran Ísírẹ́lì lọ́wọ́, Jèhófà sì dá a lóhùn.+
9 Sámúẹ́lì wá mú ọ̀dọ́ àgùntàn kan tó ṣì ń mu ọmú, ó sì fi rú odindi ẹbọ sísun+ sí Jèhófà; Sámúẹ́lì ké pe Jèhófà pé kó ran Ísírẹ́lì lọ́wọ́, Jèhófà sì dá a lóhùn.+