Òwe 20:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Abanijẹ́ ń sọ ọ̀rọ̀ àṣírí kiri;+Má ṣe bá ẹni tó fẹ́ràn láti máa ṣòfófó* kẹ́gbẹ́.