Òwe 20:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Nígbà tí ọba bá jókòó sórí ìtẹ́ láti dájọ́,+Ó máa ń fi ojú rẹ̀ yẹ ọ̀ràn wò kí ó lè mú gbogbo ìwà ibi kúrò.+
8 Nígbà tí ọba bá jókòó sórí ìtẹ́ láti dájọ́,+Ó máa ń fi ojú rẹ̀ yẹ ọ̀ràn wò kí ó lè mú gbogbo ìwà ibi kúrò.+