-
Ìdárò 1:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Láti ibi gíga ló ti rán iná sínú egungun mi,+ ó sì jó ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn.
Ó ti ta àwọ̀n fún ẹsẹ̀ mi; ó mú kí n pa dà sẹ́yìn.
Ó ti sọ mí di obìnrin tí a pa tì.
Láti àárọ̀ ṣúlẹ̀ ni mò ń ṣàìsàn.
-