Jóòbù 19:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Egungun mi lẹ̀ mọ́ awọ ara mi àti ẹran ara mi,+Awọ eyín mi ni mo sì fi yè bọ́. Òwe 17:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ọkàn tó ń yọ̀ jẹ́ oògùn tó dára fún ara,*+Àmọ́ ẹ̀mí tí ìdààmú bá máa ń tánni lókun.*+