Sáàmù 139:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Lójú tèmi, àwọn ìrònú rẹ mà ṣeyebíye o!+ Ọlọ́run, àròpọ̀ iye wọn mà pọ̀ o!+ 18 Tí mo bá ní kí n máa kà wọ́n, wọ́n pọ̀ ju iyanrìn lọ.+ Nígbà tí mo jí, mo ṣì wà pẹ̀lú rẹ.*+
17 Lójú tèmi, àwọn ìrònú rẹ mà ṣeyebíye o!+ Ọlọ́run, àròpọ̀ iye wọn mà pọ̀ o!+ 18 Tí mo bá ní kí n máa kà wọ́n, wọ́n pọ̀ ju iyanrìn lọ.+ Nígbà tí mo jí, mo ṣì wà pẹ̀lú rẹ.*+