2 Sámúẹ́lì 12:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Dáfídì wá sọ fún Nátánì pé: “Mo ti ṣẹ̀ sí Jèhófà.”+ Nátánì dá Dáfídì lóhùn pé: “Jèhófà, ní tirẹ̀ ti dárí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ jì ọ́.*+ O ò ní kú.+ Àìsáyà 43:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Èmi, àní èmi ni Ẹni tó ń nu àwọn àṣìṣe* rẹ+ kúrò nítorí tèmi,+Mi ò sì ní rántí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ.+
13 Dáfídì wá sọ fún Nátánì pé: “Mo ti ṣẹ̀ sí Jèhófà.”+ Nátánì dá Dáfídì lóhùn pé: “Jèhófà, ní tirẹ̀ ti dárí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ jì ọ́.*+ O ò ní kú.+