Sáàmù 9:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Yóò fi òdodo ṣe ìdájọ́ ilẹ̀ ayé tí à ń gbé;*+Yóò dá ẹjọ́ òdodo fún àwọn orílẹ̀-èdè.+