-
Ẹ́kísódù 24:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Mósè wá kọ gbogbo ọ̀rọ̀ Jèhófà sílẹ̀.+ Ó dìde ní àárọ̀ kùtù, ó sì mọ pẹpẹ kan sísàlẹ̀ òkè náà àti òpó méjìlá (12) tó dúró fún ẹ̀yà méjìlá (12) Ísírẹ́lì.
-