2 Àwọn Ọba 19:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ní òru ọjọ́ yẹn, áńgẹ́lì Jèhófà jáde lọ, ó sì pa ọ̀kẹ́ mẹ́sàn-án ó lé ẹgbẹ̀rún márùn-ún (185,000) ọkùnrin nínú ibùdó àwọn ará Ásíríà.+ Nígbà tí àwọn èèyàn jí láàárọ̀ kùtù, wọ́n rí òkú nílẹ̀ bẹẹrẹbẹ.+ Lúùkù 1:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Áńgẹ́lì náà sọ fún un pé: “Èmi ni Gébúrẹ́lì,+ tó ń dúró nítòsí, níwájú Ọlọ́run,+ a rán mi láti bá ọ sọ̀rọ̀, kí n sì kéde ìhìn rere yìí fún ọ.
35 Ní òru ọjọ́ yẹn, áńgẹ́lì Jèhófà jáde lọ, ó sì pa ọ̀kẹ́ mẹ́sàn-án ó lé ẹgbẹ̀rún márùn-ún (185,000) ọkùnrin nínú ibùdó àwọn ará Ásíríà.+ Nígbà tí àwọn èèyàn jí láàárọ̀ kùtù, wọ́n rí òkú nílẹ̀ bẹẹrẹbẹ.+
19 Áńgẹ́lì náà sọ fún un pé: “Èmi ni Gébúrẹ́lì,+ tó ń dúró nítòsí, níwájú Ọlọ́run,+ a rán mi láti bá ọ sọ̀rọ̀, kí n sì kéde ìhìn rere yìí fún ọ.