Sáàmù 103:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 103 Jẹ́ kí n* yin Jèhófà;Kí gbogbo ohun tó wà nínú mi yin orúkọ mímọ́ rẹ̀.