2 Sámúẹ́lì 22:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ó gun kérúbù,+ ó sì ń fò bọ̀. A rí i lórí ìyẹ́ apá áńgẹ́lì kan.*+ Jóòbù 38:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Jèhófà wá dá Jóòbù lóhùn látinú ìjì,+ ó ní: