Sáàmù 37:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Fi ọ̀nà rẹ lé Jèhófà lọ́wọ́;*+Gbẹ́kẹ̀ lé e, yóò sì gbé ìgbésẹ̀ nítorí rẹ.+ 6 Yóò mú kí òdodo rẹ yọ bí ọjọ́,Àti ìwà títọ́ rẹ bí oòrùn ọ̀sán gangan.
5 Fi ọ̀nà rẹ lé Jèhófà lọ́wọ́;*+Gbẹ́kẹ̀ lé e, yóò sì gbé ìgbésẹ̀ nítorí rẹ.+ 6 Yóò mú kí òdodo rẹ yọ bí ọjọ́,Àti ìwà títọ́ rẹ bí oòrùn ọ̀sán gangan.