Oníwàásù 10:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Oúnjẹ* wà fún ẹ̀rín, wáìnì sì ń mú kí èèyàn gbádùn ayé;+ àmọ́ owó la fi ń ṣe ohun gbogbo tí a nílò.+
19 Oúnjẹ* wà fún ẹ̀rín, wáìnì sì ń mú kí èèyàn gbádùn ayé;+ àmọ́ owó la fi ń ṣe ohun gbogbo tí a nílò.+