Jeremáyà 8:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Kódà ẹyẹ àkọ̀ tó ń fò lójú ọ̀run mọ àkókò rẹ̀;*Oriri àti ẹyẹ olófèéèré àti ẹ̀gà* kì í yẹ àkókò tí wọ́n máa pa dà.* Àmọ́ àwọn èèyàn mi ò mọ ìdájọ́ Jèhófà.”’+
7 Kódà ẹyẹ àkọ̀ tó ń fò lójú ọ̀run mọ àkókò rẹ̀;*Oriri àti ẹyẹ olófèéèré àti ẹ̀gà* kì í yẹ àkókò tí wọ́n máa pa dà.* Àmọ́ àwọn èèyàn mi ò mọ ìdájọ́ Jèhófà.”’+