Jẹ́nẹ́sísì 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ọlọ́run ṣe orísun ìmọ́lẹ̀ ńlá méjì, èyí tó tóbi á máa yọ ní ọ̀sán,+ èyí tó kéré á sì máa yọ ní òru, ó sì dá àwọn ìràwọ̀.+ Sáàmù 19:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó máa ń jáde láti ìkángun kan ọ̀run,Á sì yí lọ dé ìkángun kejì;+Kò sí nǹkan kan tó fara pa mọ́ kúrò nínú ooru rẹ̀. Jeremáyà 31:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Ẹni tó ń mú kí oòrùn máa tan ìmọ́lẹ̀ ní ọ̀sán,Tó sì ṣe òfin* pé kí òṣùpá àti àwọn ìràwọ̀ máa tàn ní òru,Ẹni tó ń ru òkun sókè, tó sì ń mú kí ìgbì rẹ̀ máa pariwo,Ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun:+
16 Ọlọ́run ṣe orísun ìmọ́lẹ̀ ńlá méjì, èyí tó tóbi á máa yọ ní ọ̀sán,+ èyí tó kéré á sì máa yọ ní òru, ó sì dá àwọn ìràwọ̀.+
6 Ó máa ń jáde láti ìkángun kan ọ̀run,Á sì yí lọ dé ìkángun kejì;+Kò sí nǹkan kan tó fara pa mọ́ kúrò nínú ooru rẹ̀.
35 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Ẹni tó ń mú kí oòrùn máa tan ìmọ́lẹ̀ ní ọ̀sán,Tó sì ṣe òfin* pé kí òṣùpá àti àwọn ìràwọ̀ máa tàn ní òru,Ẹni tó ń ru òkun sókè, tó sì ń mú kí ìgbì rẹ̀ máa pariwo,Ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun:+