Sáàmù 147:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó ń fún àwọn ẹranko lóúnjẹ,+Àwọn ọmọ ẹyẹ ìwò tó ń kígbe fún oúnjẹ.+