Nehemáyà 9:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Ìwọ nìkan ṣoṣo ni Jèhófà;+ ìwọ lo dá ọ̀run, àní ọ̀run àwọn ọ̀run àti gbogbo ọmọ ogun wọn, ayé àti gbogbo ohun tó wà lórí rẹ̀, àwọn òkun àti gbogbo ohun tó wà nínú wọn. O pa gbogbo wọn mọ́, àwọn ọmọ ogun ọ̀run sì ń forí balẹ̀ fún ọ.
6 “Ìwọ nìkan ṣoṣo ni Jèhófà;+ ìwọ lo dá ọ̀run, àní ọ̀run àwọn ọ̀run àti gbogbo ọmọ ogun wọn, ayé àti gbogbo ohun tó wà lórí rẹ̀, àwọn òkun àti gbogbo ohun tó wà nínú wọn. O pa gbogbo wọn mọ́, àwọn ọmọ ogun ọ̀run sì ń forí balẹ̀ fún ọ.