Jẹ́nẹ́sísì 1:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ọlọ́run sì dá àwọn ẹran ńlá inú òkun àti gbogbo ohun alààyè* tó ń gbá yìn-ìn nínú omi ní irú tiwọn àti àwọn ẹ̀dá abìyẹ́ ní irú tiwọn. Ọlọ́run sì rí i pé ó dára.
21 Ọlọ́run sì dá àwọn ẹran ńlá inú òkun àti gbogbo ohun alààyè* tó ń gbá yìn-ìn nínú omi ní irú tiwọn àti àwọn ẹ̀dá abìyẹ́ ní irú tiwọn. Ọlọ́run sì rí i pé ó dára.