Jóòbù 41:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 “Ṣé o lè fi ìwọ ẹja mú Léfíátánì,*+Àbí o lè fi okùn de ahọ́n rẹ̀ mọ́lẹ̀?