Jóòbù 33:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ̀mí Ọlọ́run ló ṣẹ̀dá mi,+Èémí Olódùmarè fúnra rẹ̀ ló sì fún mi ní ìyè.+ Ìṣe 17:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Torí ipasẹ̀ rẹ̀ ni a fi ní ìyè, tí à ń rìn, tí a sì wà, àní gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ àwọn kan lára àwọn akéwì yín tó sọ pé, ‘Nítorí àwa náà jẹ́ ọmọ* rẹ̀.’
28 Torí ipasẹ̀ rẹ̀ ni a fi ní ìyè, tí à ń rìn, tí a sì wà, àní gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ àwọn kan lára àwọn akéwì yín tó sọ pé, ‘Nítorí àwa náà jẹ́ ọmọ* rẹ̀.’