Sáàmù 78:55 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 55 Ó lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde níwájú wọn;+Ó fi okùn ìdíwọ̀n pín ogún fún wọn;+Ó mú kí àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì máa gbé inú ilé wọn.+
55 Ó lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde níwájú wọn;+Ó fi okùn ìdíwọ̀n pín ogún fún wọn;+Ó mú kí àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì máa gbé inú ilé wọn.+