-
Jẹ́nẹ́sísì 26:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ni Ábímélékì bá pe Ísákì, ó sì sọ pé: “Ìyàwó rẹ ni obìnrin yìí! Kí nìdí tó o fi sọ pé, ‘Àbúrò mi ni’?” Ísákì wá fèsì pé: “Ẹ̀rù ló bà mí, kí n má bàa kú torí rẹ̀+ ni mo ṣe sọ bẹ́ẹ̀.”
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 26:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ábímélékì wá sọ fún gbogbo èèyàn pé: “Tí ẹnikẹ́ni bá fọwọ́ kan ọkùnrin yìí àti ìyàwó rẹ̀, ó dájú pé ó máa kú!”
-