-
Jẹ́nẹ́sísì 41:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Àmọ́ lẹ́yìn ìyẹn, ó dájú pé ìyàn máa mú fún ọdún méje. Ó dájú pé gbogbo ohun tó pọ̀ rẹpẹtẹ nílẹ̀ Íjíbítì yóò di ohun ìgbàgbé, ìyàn yóò sì run ilẹ̀+ náà.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 42:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Àwọn ọmọkùnrin Ísírẹ́lì lọ pẹ̀lú àwọn míì tí wọ́n fẹ́ ra oúnjẹ, torí pé ìyàn náà ti dé ilẹ̀ Kénáánì.+
-
-
Ìṣe 7:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Àmọ́ ìyàn kan mú ní gbogbo Íjíbítì àti Kénáánì, ìpọ́njú ńlá ni, àwọn baba ńlá wa ò sì rí nǹkan kan jẹ.+
-