Jẹ́nẹ́sísì 41:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Fáráò bá ránṣẹ́ pe Jósẹ́fù,+ wọ́n sì sáré mú un wá látinú ẹ̀wọ̀n.*+ Ó fá irun rẹ̀, ó pààrọ̀ aṣọ rẹ̀, ó sì wọlé lọ bá Fáráò.
14 Fáráò bá ránṣẹ́ pe Jósẹ́fù,+ wọ́n sì sáré mú un wá látinú ẹ̀wọ̀n.*+ Ó fá irun rẹ̀, ó pààrọ̀ aṣọ rẹ̀, ó sì wọlé lọ bá Fáráò.