-
Ẹ́kísódù 1:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ẹ jẹ́ ká dọ́gbọ́n kan. Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ṣe ni wọ́n á máa pọ̀ sí i. Tí ogun bá sì dé, wọ́n á dara pọ̀ mọ́ àwọn ọ̀tá wa láti gbógun jà wá, wọ́n á sì kúrò nílùú.”
-