Ẹ́kísódù 4:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Jèhófà wá bínú sí Mósè, ó sì sọ pé: “Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ+ tó jẹ́ ọmọ Léfì ńkọ́? Mo mọ̀ pé ó lè sọ̀rọ̀ dáadáa. Ó sì ti ń bọ̀ wá bá ọ níbí báyìí. Tó bá rí ọ, inú rẹ̀ yóò dùn.+ Ẹ́kísódù 7:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Wò ó, mo ti mú kí o dà bí Ọlọ́run* fún Fáráò, Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ yóò sì di wòlíì rẹ.+
14 Jèhófà wá bínú sí Mósè, ó sì sọ pé: “Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ+ tó jẹ́ ọmọ Léfì ńkọ́? Mo mọ̀ pé ó lè sọ̀rọ̀ dáadáa. Ó sì ti ń bọ̀ wá bá ọ níbí báyìí. Tó bá rí ọ, inú rẹ̀ yóò dùn.+
7 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Wò ó, mo ti mú kí o dà bí Ọlọ́run* fún Fáráò, Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ yóò sì di wòlíì rẹ.+