Ẹ́kísódù 10:22, 23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Mósè na ọwọ́ rẹ̀ sí ọ̀run, òkùnkùn biribiri sì ṣú bo gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì fún ọjọ́ mẹ́ta.+ 23 Wọn ò rí ara wọn, ìkankan nínú wọn ò sì kúrò níbi tó wà fún ọjọ́ mẹ́ta; àmọ́ ìmọ́lẹ̀ wà níbi tí gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń gbé.+
22 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Mósè na ọwọ́ rẹ̀ sí ọ̀run, òkùnkùn biribiri sì ṣú bo gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì fún ọjọ́ mẹ́ta.+ 23 Wọn ò rí ara wọn, ìkankan nínú wọn ò sì kúrò níbi tó wà fún ọjọ́ mẹ́ta; àmọ́ ìmọ́lẹ̀ wà níbi tí gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń gbé.+