-
Ẹ́kísódù 3:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Kí obìnrin kọ̀ọ̀kan béèrè àwọn ohun èlò fàdákà àti wúrà pẹ̀lú aṣọ lọ́wọ́ ọmọnìkejì rẹ̀ àti obìnrin tó ń gbé nílé rẹ̀, kí ẹ sì fi wọ àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin yín; ẹ ó sì gba tọwọ́ àwọn ará Íjíbítì.”+
-