Nọ́ńbà 33:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọ́n kúrò ní Rámésésì+ ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù+ kìíní. Ọjọ́ tó tẹ̀ lé Ìrékọjá+ gangan ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi ìgboyà* jáde níṣojú gbogbo àwọn ará Íjíbítì.
3 Wọ́n kúrò ní Rámésésì+ ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù+ kìíní. Ọjọ́ tó tẹ̀ lé Ìrékọjá+ gangan ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi ìgboyà* jáde níṣojú gbogbo àwọn ará Íjíbítì.