Ẹ́kísódù 14:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tún rí agbára* ńlá tí Jèhófà fi bá àwọn ará Íjíbítì jà, àwọn èèyàn náà wá bẹ̀rẹ̀ sí í bẹ̀rù Jèhófà, wọ́n sì ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà àti Mósè ìránṣẹ́ rẹ̀.+
31 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tún rí agbára* ńlá tí Jèhófà fi bá àwọn ará Íjíbítì jà, àwọn èèyàn náà wá bẹ̀rẹ̀ sí í bẹ̀rù Jèhófà, wọ́n sì ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà àti Mósè ìránṣẹ́ rẹ̀.+