-
Nọ́ńbà 16:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Ojú ẹsẹ̀ ni wọ́n kúrò nítòsí àgọ́ Kórà, Dátánì àti Ábírámù ní gbogbo àyíká wọn. Dátánì àti Ábírámù sì jáde wá, wọ́n dúró sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ wọn, pẹ̀lú àwọn ìyàwó wọn àti àwọn ọmọ wọn, títí kan àwọn ọmọ wọn kéékèèké.
-