Diutarónómì 32:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 O gbàgbé Àpáta+ tó jẹ́ bàbá rẹ,O ò sì rántí Ọlọ́run tó bí ọ.+