-
Diutarónómì 1:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Ẹ̀ ń ráhùn ṣáá nínú àwọn àgọ́ yín, ẹ sì ń sọ pé, ‘Torí Jèhófà kórìíra wa ló ṣe mú wa kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì láti fi wá lé àwọn Ámórì lọ́wọ́, kí wọ́n lè pa wá run.
-