Nọ́ńbà 25:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Iye àwọn tí àjàkálẹ̀ àrùn náà pa jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́rìnlélógún (24,000).+ 1 Kọ́ríńtì 10:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Bákan náà, kí a má ṣe ìṣekúṣe,* bí àwọn kan nínú wọn ti ṣe ìṣekúṣe,* tí ẹgbẹ̀rún mẹ́tàlélógún (23,000) lára wọn fi kú ní ọjọ́ kan ṣoṣo.+
8 Bákan náà, kí a má ṣe ìṣekúṣe,* bí àwọn kan nínú wọn ti ṣe ìṣekúṣe,* tí ẹgbẹ̀rún mẹ́tàlélógún (23,000) lára wọn fi kú ní ọjọ́ kan ṣoṣo.+