Nọ́ńbà 20:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Lẹ́yìn náà, Mósè àti Áárónì pe ìjọ náà jọ síwájú àpáta náà, ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ọlọ̀tẹ̀! Ṣé látinú àpáta+ yìí ni ká ti fún yín lómi ni?”
10 Lẹ́yìn náà, Mósè àti Áárónì pe ìjọ náà jọ síwájú àpáta náà, ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ọlọ̀tẹ̀! Ṣé látinú àpáta+ yìí ni ká ti fún yín lómi ni?”