Àìsáyà 2:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí o ti pa àwọn èèyàn rẹ, ilé Jékọ́bù tì.+ Torí àwọn nǹkan tó wá láti Ìlà Oòrùn ti kún ọwọ́ wọn;Wọ́n ń pidán+ bí àwọn Filísínì,Àwọn ọmọ àjèjì sì pọ̀ láàárín wọn.
6 Torí o ti pa àwọn èèyàn rẹ, ilé Jékọ́bù tì.+ Torí àwọn nǹkan tó wá láti Ìlà Oòrùn ti kún ọwọ́ wọn;Wọ́n ń pidán+ bí àwọn Filísínì,Àwọn ọmọ àjèjì sì pọ̀ láàárín wọn.