-
Àwọn Onídàájọ́ 3:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ni Jèhófà bá bínú gidigidi sí Ísírẹ́lì, ó sì fi wọ́n lé Kuṣani-ríṣátáímù ọba Mesopotámíà* lọ́wọ́. Ọdún mẹ́jọ ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi sin Kuṣani-ríṣátáímù.
-