18 Nígbàkigbà tí Jèhófà bá yan àwọn onídàájọ́ fún wọn,+ Jèhófà máa ń wà pẹ̀lú onídàájọ́ náà, ó sì máa ń gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wọn ní gbogbo ọjọ́ tí onídàájọ́ náà bá fi wà; Jèhófà ṣàánú wọn+ torí pé àwọn tó ń ni wọ́n lára+ àtàwọn tó ń fìyà jẹ wọ́n mú kí wọ́n máa kérora.